Toyin Abraham celebrates her man on his birthday

0

It’s Toyin Abraham’s husband birthday today. And to celebrate her beau and father of her son, Kolawole Ajeyemi, Toyin took to instagram to shower him with love poem and praises. She wrote;

”Oko mi, ololufe mi, olowo ori mi @kolawoleajeyemi
Iwo ni eledumare fi se aso bo ihoho mi,
Iwo ni ete ti o je ki eyin mi di apoti isana
Iwo ni ejika ti ko je ki aso o ye lorun mi
Kolawole, iwo ni orun ti o gbe ori emi Toyin duro

Ni ojo eni to o je ayajo ojo ti a bi e saye, ni agbara eledumare, ire gbogbo ma wa e ri

Rere ni oju owo n ri, rere bayi ni oju e ma ma ri.
Eyan bi esu, esu bi eyan ti o ma n fi ikoro si nkan ti o n dun o ni fi ikoro si Ife wa ni agbara Olorun

Iwo ni irawo owuro mi, Irawo e o ni wo okunkun

Akolawole, Odun tuntun yi a san e s’owo, a san e s’omo, a san e si alafia ati emi gigun.
Happy birthday my love. Ife wa, titi laye laye ni.
I love you now and forever❤️❤️❤️❤️❤️”

Follow Us on Facebook – @LadunLiadi; Instagram – @LadunLiadi; Twitter – @LadunLiadi; Youtube – @LadunLiadiTV for updates

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here