Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún. Ẹdúnjobí Ọmọ ẹdun tíí ṣeré orí igi Ọ́-bẹ́-kẹ́ṣé-bẹ́-kàṣà, Ó fẹsẹ̀ méjèèjì bẹ sílé alákìísa; Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá, Tíí gbàdọ̀bálẹ̀ lọ́wọ́ baba tó bí í lọ́mọ. Wínrinwínrin lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀. Tani o bi ibeji ko n'owo?

Ejire wun mi...Cute babies
ReplyDeleteẸ̀jìrẹ́ ará ìṣokún.
ReplyDeleteẸdúnjobí
Ọmọ ẹdun tíí ṣeré orí igi
Ọ́-bẹ́-kẹ́ṣé-bẹ́-kàṣà,
Ó fẹsẹ̀ méjèèjì bẹ sílé alákìísa;
Ó salákìísà donígba aṣọ.
Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá,
Tíí gbàdọ̀bálẹ̀ lọ́wọ́ baba tó bí í lọ́mọ.
Wínrinwínrin lójú orogún
Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀.
Tani o bi ibeji ko n'owo?
Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún.

They grow so quickly
ReplyDeleteCuties
ReplyDelete